Ha! Terrific message for Tinubu from Ifa Agboniregun
Ifa so pe..
.....
Imagine this
But why is this?
And Ifa has been
Accurate and most precise.
And whatever Ifa Says is not only a
Confirmed but also Signed , sealed and delivered.
For those who do not understand Yoruba , the dialect of Ifa, just scrolled down to the last four lines of this article.
He says..
Gedegbe lowo nyo ju Ori
Iwaju opon o gbo
Eyin opon o gba
Olumu Otun, olukanran OSI
Aarin opon Ita orun
Adifa fun Bola Ahmed omo Tinubu
Nigbati awon PDP, Labour Party, ati awon amugbalegbe pejo ni nibi gbogbo
Lati fenu obu wi tire
Won ni ki Bola Ahmed Omo Tinubu maa so wipe:
Osalala loruko ti a pe aye
Obekisi Jana loruko esu Odara
Adifa fun rikisi awon aje PDP ati awon aje Labour ati awon aje alatako
ibi gbogbo,
Imo enini kii dojo ale
Emo ajao ki ja
Ajaro ni ti adan
Eja kii sere erupe dojo ale
Ajantuka ni ti agbaarin,
Ibi ti Ojo ba ti ba Ojo
Ibe lo maa pasi
Gbogbo rikisi, efufulele ma dawon nu
Efufulele
Gbogbo abamoda won, efufulele
Maa dawon nu, efufulele.
Sugbon nipa ti Bola Omo Tinubu
Kenke loruko ti a pori
Atari pakata loruko ona
Ona la, Bola Omo Tinubu fe wo Aso Rock
Omo.Abibatu Mogaji fe di Olori
Orile Ede Nigeria
Ona laaaaaaaaa
Aboru boye ni tifa o......
Aseyori ni ti Oorun
Gedegede lowo yo jori
Ogagan ona lalake nso
Awise ni Tedumare
Oro talagemo ba da
Ni orisa oke ngba
Sise sise ni ti Ilakose
Oti ri be
Oti se be
Bola Ahmed omo Tinubu
Oo ma bori ota
Oo ma rehin odi.
Gedegbe lowo nyo jori
Aseyori ni tie
Emi ko oo
Ifa loso be
That Bola Ahmed Tinubu
Will be victorious
That he is the next President of Nigeria
QED.
Signed
Wale Ojo- Lanre
Member, Special Ops / New Media , APC PCC
08033490986
Usi- Ekiti.
No comments:
Post a Comment