Saturday 19 November 2022

Ha! Terrific message for Tinubu from Ifa Agboniregun


 Ha! Terrific message for Tinubu from Ifa Agboniregun 

Ifa so pe..

.....

Imagine this 

But why is this?

And Ifa  has been

Accurate and most precise.

And whatever Ifa Says is not only a

Confirmed but also Signed , sealed and delivered.

For those who do not understand Yoruba , the dialect of Ifa, just scrolled down to the last four lines of this article. 

He says..


Gedegbe lowo nyo ju Ori


Iwaju opon o gbo

Eyin opon o gba

Olumu Otun, olukanran OSI

Aarin opon Ita orun

Adifa fun Bola Ahmed omo Tinubu 

Nigbati awon PDP, Labour Party, ati awon amugbalegbe  pejo ni nibi gbogbo

Lati fenu obu wi tire

Won ni ki Bola Ahmed Omo Tinubu maa so wipe:

Osalala loruko ti a pe aye

Obekisi Jana loruko esu Odara

Adifa fun rikisi awon aje PDP ati  awon aje Labour  ati awon aje alatako 

ibi gbogbo,

Imo enini kii dojo ale

Emo ajao ki ja

Ajaro ni ti adan

Eja kii sere erupe dojo ale

Ajantuka ni ti agbaarin,

Ibi ti Ojo ba ti ba Ojo

Ibe lo maa pasi

Gbogbo rikisi, efufulele ma dawon nu

Efufulele

Gbogbo abamoda won, efufulele

Maa dawon nu, efufulele.

Sugbon nipa ti Bola Omo Tinubu

Kenke loruko ti a pori

Atari pakata loruko ona

Ona la, Bola Omo Tinubu  fe wo Aso Rock 

Omo.Abibatu Mogaji fe di Olori 

Orile Ede Nigeria 

Ona laaaaaaaaa

Aboru boye ni tifa o......

Aseyori ni ti Oorun

Gedegede lowo yo jori

Ogagan ona lalake nso

Awise ni Tedumare 

Oro talagemo ba da

Ni orisa oke ngba

Sise sise ni ti Ilakose

Oti ri be 

Oti se be 

Bola Ahmed omo Tinubu 

Oo ma bori ota

Oo ma rehin odi.

Gedegbe lowo nyo jori

Aseyori ni tie 

Emi ko oo

Ifa loso be 

That Bola Ahmed Tinubu 

Will be victorious 

That he is the next President of Nigeria

QED. 

Signed 

Wale Ojo- Lanre 

Member, Special Ops / New Media , APC PCC 

08033490986

Usi- Ekiti.